Lyrics of Eru Ogbo re Bami

Eru Ogo re bamiEru ogo re bami oEleni ogoOnite ogoAlade ogoOlolainu ogoElewa ogoKikidaogo ogoAkodaogo ogoOgoninu ogoAsaju ogoIgbeyin ogoEru ogo re bami o1.Boti n gbe ninu ogoO n Sogo Lori ite oOgo lo wo lasoOloju ogo niEda Orun fogo fun aramanda ogo to yii won kaBaba ologo julo to da ohun gbogbo pelu ogo.2.Boti leruniyi toIte idajo taanu togoOgo otun iseju si isejuEwa ti o lakaweNigbogbo igba sigbaOdodo logo reAwon orile -ede gbogbo nsola Lori ogo re3.Olorun to ta sanmo pelu ogoIwo lasaju ologo to leruniyi iba baba ibaCall: alogoleruResponse: tolokeCall: eleruniyiResponse: tonileCall: onile olaResponse: alade ogoCall: ofi kikida ogo
Share with friends.

By Matex

Leave a Reply